Lóde òní, ọ̀pọ̀ ṣọ́ọ̀ṣì ló ń ṣe ìjọsìn ní Ọjọ́-Àìkú, ṣùgbọ́n ó jẹ́ ìlànà ènìyàn kan tí a gbé kalẹ̀ nígbà tí Olú-ọba Kọnsitatáìnì kéde Ọjọ́-Àìkú gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ ìsinmi gbogbogbò àti ọjọ́ ìjọsìn ní AD 321.
Ọjọ́ Ìsinmi ọjọ́ keje, tí Ọlọ́run ṣèlérí àwọn ìbùkún àti ìjẹ́mímọ́, tí ó sì pàṣẹ fún wa láti pa á mọ́ títí di òpin ọjọ́ ayé, jẹ́ Ọjọ́-Àbaméta.
Lónìí, ilé-ijọsin kan ṣoṣo tí ó tọju Ọjọ́ Ìsinmi ní Ọjọ́-Àbaméta ní ibámu pẹ̀lú ọrọ́ Ọlọ́run World Mission Society Church of God.
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy